Ifihan 22:2-21

Ariwo si jade wa lati inu Tempili orun wa,latori ite wipe, o pari.

Ifihan 21:22-22:1

Nitori ki ale imurakale fun oba ti o nbo

Ifihan 21:19

A ti ijoba won ti o kun fun okunkun osi mu iya ba ahon won

Ifihan 21:6

Awon eniyan si je iya nipase ebu na osi dabi oru ni ara won

Ifihan 21:2-5

Angeli na si wipe awon olododo ti a ti fi emi won sofo nitori ti e

Ifihan 20:14-21:2

Gbogbo Eda alaye lo si si inu okun na.

Ifihan 20:9-13

Opolopo lo si ni ami kokoro na ni ogangan ori won

Ifihan 20:4-9

Awon abo mejeje na si wa fun ami

Ifihan 20:1

Orin halleluyah yio si gbenu awon eniyan kaan ni ojo na

Ifihan 19:11

Ojo eyi ti nse ojo idajo gbogbo araiye

Ifihan 19:2-11

Nitori won sinmi ninu gbogbo lala won, nitori ise won ntowo leyin