Awon Onidajo 1:1-3:11
-
Awon Onidajo 1:1-3:11
Close
Josua 23-24
Josua so wipe ki won mura gidigidi lati toju ati lati se ohun gbogbo ti o wa ninu ofin Mose
Josua 21-22
Olori awon baba awon omo Lefi sunmo Eleasari alufa,won gba ilu lati maa gbe ati agbegbe won.
Josua 19-20
Olorun so fun awon omo Isreli ki won yan ilu abo fun ara won
Josua 15-18
Ipin orisirisi eya ni Isreli
Josua 12-14
Josua gbo osi dagba ni ojo, sibe ile si ku lati gba fun Oluwa
Josua 10:15-11:23
Bi o tile je wipe awon oba dide lati kolu Josua, Olorun ran Josua lowo o si fi won lee lowo.
Josua 8:30-10:14
Olorun dariji awon omo Isreli nigbati won ti pa Akai ati idile run nitori ese ti o se si OLorun
Josua 7:1-8:29
Isreli se si Olorun. Ilu Ai si bori won ni ogun
Josua 6
Olorun so fun Josua pe ko yi ilu jeriko ka pelu awon Alufa ni emeje.
Josua 4:19-5:15
Awon okuta ti Josua to won yi ni ofi se ami lati se iranti ati lati je ki awon omo lehin ola mo pe won la jodani koja ni ile gbigbe